Jump to content

Mósè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
nbóòò
nbóòò
Awon ara Egipti ri sinu omi leyin ti Mose pinya Okun Pupa

Ninu Bibeli Mósè ni asiwaju esin, amuofinwa ati woli. Oluwa-Olorun ti lo Mose lati pinya Okun Pupa. Oluwa-Olorun ti lo Mose lati gba awon omo Israeli lati Egipti ati lati gbé won si Ile Ileri.