Maad Saloum

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Maad Saloum (wọ́n tún ń pè wọ́n ní:Maad a Saloum, Mad Saloum, Maat Saloum, Bour Saloum, Bur Saloum, etc.) túmọ̀ sí ọba Saloum,[1][2]èdè Serer. Ìjọba Saloum ní ayé àtijó tí jẹ́ ara orílẹ̀ èdè Senegal ìsinsìnyí. Orúkọ tí wọ́n ń pe àwọn ọba wọn ni Maad tàbí Mad (wọ́n tún ma ń pè wọ́n ní Maat lẹ́kokan). Wọ́n tún ma ń lọ orúkọ náà láti pe àwọn ọba Serer.[3][4][5][6][7]

Láàrin ọdún 1493 sí 1969 (ní àsìkò Guelowar), àwọn ọba bí ọ̀kan lé ládọ́tá Maad Saloum (ọba Saloum). Ní àsìkò Guelowar, Maad Saloum Mbegan Ndour ni ẹni àkọ́kọ́ láti di ọba láti ìran Guelowar láti darí Saloum. Maad Saloum Fode N'Gouye Joof ni ẹni tí ó jọba kẹ́yìn ní Saloum. Ó jọba láàrin ọdún 1935 sí 1969 - ọdún tí ó papòdà.[8][9]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Dioum, Baïdy, La trajectoire de Léopold Sédar Senghor: du terroir à l'universel, p 33, Harmattan, 2010, ISBN 2296120520
  2. Klein, Martin A., Islam and Imperialism in Senegal. Sine-Saloum, 1847-1914, Edinburgh University Press, 1968, p. 8
  3. Oliver, Roland, Fage, John Donnelly & Sanderson, G. N., The Cambridge History of Africa, Cambridge University Press, 1985, p. 214 ISBN 0521228034
  4. Faal, Dawda, Peoples and empires of Senegambia: Senegambia in history, AD 1000-1900, Saul's Modern Printshop, 1991, p. 17
  5. Ajayi, F. Ade et Crowder, Michael, History of West Africa, vol. 1, Longman, 1985, p. 468 ISBN 0582646839
  6. Galvan, Dennis C., The State Must be Our Master of Fire, University of California Press, 2004, p. 270 ISBN 9780520235915
  7. Marcel Mahawa Diouf, Lances mâles : Léopold Sédar Senghor et les traditions sérères, Centre d'études linguistiques et historiques par tradition orale, Niamey, 1996, p. 54
  8. Ba, Abdou Bouri, « Essai sur l’histoire du Saloum et du Rip  » (avant-propos par Charles Becker et Victor Martin), Bulletin de l'IFAN, tome 38, série B, numéro 4, octobre 1976 "Ba Abdou Bouri, Essai sur l'histoire du Saloum et du Rip". Archived from the original on 2013-04-15. Retrieved 2012-03-09.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. Klein, Martin A., Islam and Imperialism in Senegal. Sine-Saloum, 1847-1914, Edinburgh University Press, 1968, p. XV