Macy Gray
Ìrísí
Macy Gray | |
---|---|
Macy Gray ni 2008 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Natalie Renee McIntyre |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹ̀sán 1967 Canton, Ohio, United States |
Irú orin | R&B, soul, neo soul, hip hop |
Occupation(s) | Singer-songwriter, record producer, actress |
Years active | 1990–present |
Labels | Atlantic (1994-1996) Epic (1998-2004) will.i.am / Geffen (2006-2008) Concord (2009-2011) 429 (2011-) |
Associated acts | Bobby Brown, Natalie Cole, Velvet Revolver, Pharoahe Monch, The Black Eyed Peas |
Website | macygray.com |
Macy Gray (oruko abiso Natalie McIntyre, 6 September 1967 ni Canton, Ohio, USA)[1][2] je akorin-adaorin R&B ati soul, atokun awo-orin, ati osere ara Amerika to gba Ebun Grammy, o gbajumo fun ohun hiha re ati iru ikorin to jo bi Billie Holiday ati Betty Davis.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "It's a Macy, Macy world". The Guardian. 18 November 2001. http://www.guardian.co.uk/theobserver/2001/nov/18/life1.lifemagazine5. Retrieved 22 January 2012.
- ↑ Bio at All Music.com