Mae Jemison

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Mae C. Jemison)
Jump to navigation Jump to search
Mae Jemison
Arìnlófurufú NASA
Orílẹ̀-èdè ará Amẹ́ríkà
Ipò Ti fẹ̀yìntì
Ìbí Oṣù Kẹ̀wá 17, 1956 (1956-10-17) (ọmọ ọdún 63)
Decatur, Alabama
Iṣẹ́ míràn Oníwòsàn
Olùkọ́
Àkókò ní òfurufú 190 h 30 min 23 s
Ìṣàyàn 1987 NASA Group
Ìránlọṣe STS-47
Àmìyẹ́sí ìránlọṣe STS-47

Mae Carol Jemison (ọjọ́ìbí 17 October, 1956) jẹ́ oníwòsàn àti arìnlófurufú fún NASA ará ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Òhun ni obìnrin aláwòdúdú àkọ́kọ́ tó rinàjò lọ sí inú òfurufú nígbà tó rinàjò lọ pẹ̀lú Ọkọ̀-ayára Òfurufú Endeavour ní September 12, 1992.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]