Mae Jemison

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mae Jemison
Arìnlófurufú NASA
Orílẹ̀-èdèará Amẹ́ríkà
IpòTi fẹ̀yìntì
ÌbíOṣù Kẹ̀wá 17, 1956 (1956-10-17) (ọmọ ọdún 67)
Decatur, Alabama
Iṣẹ́ mírànOníwòsàn
Olùkọ́
Àkókò ní òfurufú190 h 30 min 23 s
Ìṣàyàn1987 NASA Group
ÌránlọṣeSTS-47
Àmìyẹ́sí ìránlọṣeSTS-47

Mae Carol Jemison (ọjọ́ìbí 17 October, 1956) jẹ́ oníwòsàn àti arìnlófurufú fún NASA ará ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Òhun ni obìnrin aláwòdúdú àkọ́kọ́ tó rinàjò lọ sí inú òfurufú nígbà tó rinàjò lọ pẹ̀lú Ọkọ̀-ayára Òfurufú Endeavour ní September 12, 1992.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]