Mahafali

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Mahafali Àwọn ènìyàn yìí lé ní mílíọ̀nù kan àti ààbọ̀, wọ́n ń gbé ní apá Gúúsù ìwọ̀ oòrùn Madagascar. Àgbẹ̀ àti darandaran sì ni wọ́n; wọ́n gbajú gbajà fún fínfín àti kíkun ibojì/sàréè. Wọ́n ní ìgbàgbọ́ nínú òrìṣà àkúnlẹ̀bọ, asòdì sí ẹ̀kó kristiẹni ni ìjọba wọn tẹ́lẹ̀, wọn kò ní àǹfààní láti gbọ́ nípa orúkọ Jesu. Nísisìyí ẹ̀sìn òmìnira ti wà ṣùgbọ́n ojú ọ̀nà tí kò dára ń pa ìtànkálẹ̀ ìhìnrere lára.