Mahamane Ousmane
Ìrísí
Mahamane Ousmane | |
---|---|
Mahamane Ousmane (right) on a 2005 panel with Former Presidents Ketumile Masire of Botswana (centre) and Antonio Manuel Mascarenhas Monteiro of Cape Verde (left). | |
President of Niger | |
In office April 16, 1993 – January 27, 1996 | |
Alákóso Àgbà | Mahamadou Issoufou Souley Abdoulaye Hama Amadou |
Asíwájú | Ali Saibou |
Arọ́pò | Ibrahim Baré Maïnassara |
Majority | 54.42% (2nd round 1993) |
President of the National Assembly of Niger | |
In office December 1999 – May 2009 | |
Speaker of ECOWAS Parliament | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2006 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kínní 1950 Zinder, Niger, French West Africa |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerien |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic and Social Convention-Rahama |
Mahamane Ousmane (ojoibi January 20, 1950[1]) je oloselu ara Niger. Ohun ni Aare adiboyan akoko ati ikerin ile Nijer, lati 16 April 1993[2] titi igba ti o je lole kuro pelu ifipagbajoba ologun ni 27 January 1996.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "President of the National Assembly of Niger Mahamane Ousmane Elected President of the IPU Committee on Human Rights of Parliamentarians", Inter-Parliamentary Union, press release no. 179, 15 January 2004.
- ↑ Background Notes: Niger, July 1994, U.S. Department of State.