Malcolm Ohanwe
Malcolm Ohanwe | |
---|---|
Ohanwe in 2009 | |
Ọjọ́ìbí | Malcolm Oscar Uzoma Ohanwe Munich, Germany |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Ludwig Maximilian University of Munich |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2009–present |
Malcolm Ohanwe (tí wọ́n bí ní ọdún 1993 ní Munich ) jẹ́ akọroyin, ará German-Nigerian, gbajúgbajà lórí ẹ̀rọ-ayélujára àti olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán. eniyan media ati agbalejo TV.
Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Malcolm Ohanwe tí wọ́n bí ní Munich, ní Germany, ìyá rẹ̀ jẹ́ ará Palestine, nígbà tí bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Naijiria.[1][2] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi akọ̀ròyìn lẹ́yìn tó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ìwé girama, gẹ́gẹ́ bí òǹkọ̀wé fún German television network ProSieben, àti bíi olóòtú ilé-iṣẹ́ German kan, tí orúkọ wọn lórí ẹ̀rọ-ayélujára ń jẹ́ Rap2Soul.de.[3]Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa èdẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Middle Eastern Studies, àti Romance Studies ní Ludwig-Maximilians-University, ní Munich. Lẹ́yìn náà, ó kọ́ èdè Arabic, German, English, French, Italian Àti Spanish, ó sì ń fi ṣe iṣẹ́.[4]
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 2019: International Music Journalism Award. For his Wir sind zu viele: Warum deutscher Pop nicht mehr weiß bleibt (Best Work of Music Journalism, Under 30)[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ida Heinzel (24 October 2019). "089 – 8 Fragen, 9 Antworten mit Kanackische Welle". Mit Vergnügen München.
- ↑ Malcolm Ohanwe (7 January 2019). "R. Kelly scheint ein Dämon zu sein und ich wollte es nicht wahrhaben…". Rap2Soul.de.
- ↑ "Malcolm Ohanwe: Journalist (Hörfunk, Fernsehen & Online)". Piqd.
- ↑ "Malcolm Ohanwe: 60 Sekunden Fragenhagel". Bayerischer Rundfunk. 15 January 2018.
- ↑ "Winners 2019 | International Music Journalism Award".