Mambila

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Mambila Àwọn ènìyàn yìí wà ní orílẹ̀ èdè Nigeria ati Kameroon, wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lọ́na mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n wọ́n sì múlé ti àwọn ènìyàn bíi kaka, Tikong àti Bafum. Ede Mambila, ẹ̀yà Bantu ni wọ́n sì ń sọ. Àgbẹ, ọde,̣ apẹja àti ọ̀ṣìn ẹran ni ìṣe wọn. Ẹ̀sìn Mùsùlùmí àti ti ìbílẹ̀ ni wọ́n ń ṣe papọ̀. Àwọn wọnyi wa ni Orílẹ́ èdè Nigeria àti Cameroon. wọn jẹ ẹya Bantu. Awọn kaka, Tikong ati Bafun ni wọn jọ pààlà. Ẹsin ibilẹ ati ẹsin musulumi ni wọn n sin.