Manhattan Project
Agbegbe Manhattan | |
---|---|
![]() Ise agbese Manhattan ti da bombu iparun. akoko ni gbogbo ayé Awon idanwo Trinity je fi han. | |
Ìgbéṣe | 1942–1946 |
Orílẹ̀-èdè | ![]() ![]() ![]() |
Ẹ̀ka | United States Army Corps of Engineers |
Ibùjokòó | Oak Ridge, Tennessee |
Àjọ̀dún | 13 August 1942 |
Engagements | Allied Invasion of Italy Allied Invasion of France Allied Invasion of Germany Atomic bombings of Hiroshima and Nagasaki Allied Occupation of Japan |
Disbanded | 15 August 1947 |
Àwọn apàṣẹ | |
Notable commanders |
Kenneth Nichols |
Àmì-ẹ̀ṣọ́ | |
Shoulder patch that was adopted in 1945 for the Manhattan District | ![]() |
Manhattan Project emblem (unofficial) | ![]() |

The Manhattan Project ni oruko amioro fun iseowo to waye nigba Ogun Agbaye Keji lati seda bombu atomu akoko. Orile-ede Amerika lo lewaju iseowo yi pelu ikopa Britani ati Kanada.
Kini je awon bombu iparun?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon bombu iparun je awon ohun ti o le parun awon opolopo ohun. Awon bombu iparun je lweu gidigan, nitori ti e ba lo awon bombu iparun, ti e ba ti pari, e ko ma ri kankan, nitori bombu iparun won parun ohun gbogbo.
Awon bombu ipraun ewu ju ibon, ọrun ati ọfà, kànnàkànnà, opa, oko, ati gbogbo ohun ijagun ni gbogbo ayé. Aon bombu ipraun je ewu gidigan!
Se awon orile-ede ni awon bombu iparun?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ah, bee ni oh! Awon orile-ede dabi Amerika, China, Russia, Israeli, won ni awon bombu iparun sùgbon Afrika, won ko ni awon bombu iparun nitori won fe se itoju ti agbayé wa.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |