Jump to content

Manning Marable

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Manning Marable
Marable in 2007
Ọjọ́ìbíWilliam Manning Marable
(1950-05-13)Oṣù Kàrún 13, 1950
Dayton, Ohio, U.S.
AláìsíApril 1, 2011(2011-04-01) (ọmọ ọdún 60)
New York City, New York, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gíga
Olólùfẹ́Leith Mullings

William Manning Marable (May 13, 1950 – April 1, 2011)[1] ọ̀mọ̀wé ará Amẹ́ríkà. Marable jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ètò ìgboro, ìtàn àti Àwọn Ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkàYunifásítì Kòlúmbíà.[1] Marable ló jẹ́ ọlùdásílẹ̀ àti olùdarí Ilé-ẹ̀kọ́ fún Ìwadìí nínú àwọn Ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.[2] Ó kọ ìwé tó pọ̀, ó sì kópa nínú akitiyan òṣèlú onílọsíwájú. Kí ó tó kú ní ọdún 2011, ó ti parí ìwé-ìgbésíayè lórí Malcolm X tí àkọlẹ́ rẹ̀ únjẹ́ Malcolm X: A Life of Reinvention (2011),[3] èyí tí Marable gba Ẹ̀bùn Pulitzer fún Ìtàn fún ní ọdún 2012 lẹ́yìn tí ọ́ kú.[4]


Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]