Marc Serena
Ìrísí
Marc Serena | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Marc Serena 1983 Manresa, Spain |
Orílẹ̀-èdè | Spanish |
Iṣẹ́ | Director, producer, writer, author |
Ìgbà iṣẹ́ | 2007–present |
Marc Serena (tí wọ́n bí ní ọdún 1983) jẹ́ olùgbéré-jáde, olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Spain.[1] Ó gbajúmọ̀ fún dídarí àwọn fíìmù ìtàn-àkọọ́lẹ̀ ti ilẹ̀ Áfríkà bíi Tchindas, Peixos d'aigua dolça àti The Writer from a Country Without Bookstores.[2][3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Startseite › Autoren › Marc Serena". newspanishbooks. Archived from the original on 24 November 2021. Retrieved 27 October 2020.
- ↑ "Marc Serena: Drehbuchautor, Regisseur, Ausführender Produzent". filmstarts. Retrieved 27 October 2020.
- ↑ "Marc Serena, film director: «In Equatorial Guinea they live a tropical type of Francoism»". ultimahora. Retrieved 27 October 2020.