Margaret Ekpo
Ìrísí
Margaret Ekpo | |
---|---|
Fáìlì:Mrs Margaret Affiong Ekpo.jpg President of the Women's wing of N.C.N.C | |
Member, Regional House of Assembly | |
In office 1961–1965 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Creek Town, Nigeria Protectorate | Oṣù Kẹfà 27, 1914
Aláìsí | September 21, 2006 calabar | (ọmọ ọdún 92)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | N.C.N.C |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Dr John Udo Ekpo |
Àwọn ọmọ | Mr. Edward Effi Ekpo Major Winston Eyo Ekpo |
OlóyèMargaret Ekpo ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàdínógún oṣù Kẹsàn án ọdún 1914, jẹ́ ajàfẹ́tọ́ àwọn obìnrin olùkérò-jọ,àti olùfilọ́lẹ̀ ìkópa àwọn obìnrin nínú ìṣèlú àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì ati olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ ajìjà-n-gbara àwọn obìnrin tó gbé àsíá ìṣọ̀kan ẹ̀yà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dání.[1] Ó ṣiṣẹ́ ribi ribi pàá pàá jùlọ nínú ìjàngbara òmìnira orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kúrò lọ́wọ́ àwọn òyìnbó amúnisìn. Òun ni ó léwájú nínú ìtàpórógan tí ó fa fàákája tó wáyé láàrin sísan owó-orí ọkùnrin àti obìnrin ní ìlú Aba (Aba Women's riot) ní apá Ìlà-Oòrun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2]
Àwọn Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Toyin Falola, Adebayo Oyebade. Africa World Press, 2002, p. 374. ISBN 0-86543-998-2
- ↑ Jeremiah I. Dibua. Ashgate Publishing, Ltd, 2006, p. 68. ISBN 0-7546-4228-3