Jump to content

Margaret Oguntala

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Margaret Oguntala tí orúkọ inagi rẹ jẹ Erelu[1] jẹ́ enginia àti olùdarí fún Bamsat Nigeria Limited.[2][3][4][5] Ó ti jẹ́ igbá kejì adarí fún Nigerian Society of Engineers (NSE),[6][7] lùkédefún Association of Professional Bodies of Nigeria.[8] Ó ti ṣe alága fún Nigeria Society of Engineers ni ẹ̀yà tí Ikeja.[9]

Ó gboyè gẹ́gẹ́ bí enginia òní kẹ́míkà ni odun 1986.[10] Ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ Nigeria Society of Engineers ni ọdún 1995.[10] Òun ni adarí fún Bamsat Nigeria Limited.[11] Ó di igbá kejì adarí fún Nigerian Society of Engineers ni ọjọ́ kẹje oṣù kọkànlá ọdún 2014.[12][13][14][15][16] Ní ọjọ́ kẹẹ̀dògùn oṣù kẹsàn-án ọdún 2017, ní wọn fi sì inú Nigeria's Construction Industry Hall of Fame.[17] Ní ọdún 2014, Margaret ṣe asojú fún NSE ni Sierra Leone, tí ó sì sọ̀rọ̀ nípa kókó ìwúlò lílo àwọn ẹ̀yán tí ó tọ ni ilé iṣẹ́.[18] Ó sọ ọ̀rọ̀ nípa ti àìtó òun èlò amáyéderùn ṣe ń dekun igagbasoke orile èdè Nàìjíríà ni Àkúré níbi ètò tí àwọn NSE gbé kalẹ.[19][20] Ó wá láàrin àwọn tí ó ṣe ifowosi àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga ni ọdún 2018.[21] Ó gbà ẹ̀bùn idanimo pàtàkì láti ọ̀dọ̀ Nigeria Society of Engineers tí ẹ̀yà Ikeja ni odun 2017.[22]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Engineers, My (13 October 2017). "Engineers must place emphasis on project's quality and contribute into sustainable infrastructure development – Erelu Oguntala". My Engineers. 
  2. Engineers, My (5 October 2017). "Your Competence Has Nothing To Do With Gender – Engr Oguntala". My Engineers. 
  3. "Nigeria: Engineers Tasked On Ethics, Quality Service.". 
  4. "Engineers tasked on ethics, quality service". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News. 9 October 2017. Archived from the original on 13 February 2018. Retrieved 16 May 2020. 
  5. "Your Competence Has Nothing To Do With Gender – Oguntala". 
  6. "Women In Built Environment Should Learn To Blow Their Own Trumpet – Oguntala". 
  7. "NSE sets agenda for incoming science, technology minister -". The Eagle Online. 9 October 2015. 
  8. "APBN to collaborate with EFCC in fight against corruption". SundiataPost. 31 October 2013. 
  9. "NSE Concludes 45th AGM at Ilorin. Calls for Strategic Promotion of Sustainable Technology | The Nigerian Society of Engineers,Eket Branch". eketnse.org. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  10. 10.0 10.1 "Ẹda pamosi" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2023-06-01. Retrieved 2020-05-16. 
  11. "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2018-02-13. Retrieved 2020-05-16. 
  12. "INVESTITURE OF 15 ACEN PRESIDENT HELD IN LAGOS" (PDF). [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  13. Media, BlackHouse (10 August 2015). "2015 Annual Engineering Conference: NSE Partners FG in Pursuit of National Economic Growth". BHM. 
  14. "US Consulate, NSE, Globetech collaborate on urban sanitation". Punch Newspapers. 
  15. "Ẹda pamosi" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2023-06-01. Retrieved 2020-05-16. 
  16. Engineers, My (7 November 2014). "NSE Elects New National Executive @ WECSI2014". My Engineers. 
  17. "CED Magazine List Inductees in the Nigeria’s Construction Industry Hall of Fame, 2017". Construction & Engineering Digest (CED) Magazine. 21 September 2017. Archived from the original on 22 October 2020. Retrieved 16 May 2020. 
  18. "Sierra Leone News: Engineers should become entrepreneurs- John Sisay". Awoko Newspaper. 27 June 2014. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  19. Media, BlackHouse (10 August 2015). "Nigerian Society Of Engineers Holds Annual Conference in Akure". BHM. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  20. "Nigerian Society Of Engineers Holds Annual Conference In Akure". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 
  21. "Council for the Regulation of Engineering in Nigeria – Accreditation Visit to the University of Science and Technology Enugu". www.coren.gov.ng. Archived from the original on 2021-04-16. Retrieved 2020-05-16. 
  22. "Meritorious Service: NSE Rewards Prominent Members". YELL NEWS. 2 September 2017. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]