Jump to content

Mariam Coulibaly

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mariam Coulibaly
No. 15 – Landerneau Bretagne Basket
PositionCenter
LeagueLFB
Personal information
Born7 Oṣù Kẹ̀wá 1997 (1997-10-07) (ọmọ ọdún 27)
Bamako, Mali
NationalityMalian
Listed height1.92 m (6 ft 4 in)
Career information
NBA draft2019 / Undrafted

Mariam Coulibaly (tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹwàá ọdún 1997) jẹ́ agbábọ́ọ̀lú alájùsáwọ̀n fún orílẹ̀-èdè Mali, tí ó sì gbá bọ́ọ̀lù náà fún ẹgbẹ́ Landerneau Bretagne Basket àti Malian national team.[1]

Ó kópa níní ìdíje ti 2017 Women's Afrobasket.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]