Mariam Ndagire
Mariam Ndagire | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kàrún 1971 Kampala, Uganda |
Orílẹ̀-èdè | Ugandan |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Uganda |
Ẹ̀kọ́ |
|
Iṣẹ́ | Singer, film producer, actress, scriptwriter, film director |
Gbajúmọ̀ fún | Music and film production |
Mariam Ndagire (bíi ni ọjọ́ kerìndínlọ́gún oṣù karùn-ún ọdún 1971) jẹ́ olórin, òṣèré àti olùdarí eré lórílẹ̀-èdè Uganda.[1][2][3]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Mariam sí ìlú Kampala ní orílẹ̀ èdè Uganda sí ìdílé Sarah Nabbutto àti Prince Kizito Ssegamwenge. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Buganda Road Primary School àti Kampala High School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Makere University.[4]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ndagire bẹ̀rẹ̀ eré orí ìtàgé nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún. Ó darapọ̀ mọ́ Black Pearls ní ọdún 1987, ibẹ̀ sì ni ó ti kọ eré àkọ́kọ́ rẹ tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní Engabo Y'addako. Òun àti Kato Lubwama àti Ahraf Simwogerere jọ dá ẹgbẹ́ Diamonds' Ensemble kalẹ̀.[5] Ní ọdún 2015, ó jẹ́ ìkan lára àwọn tí ó ṣe adájọ́ fún ètò àmì ẹ̀yẹ tí AFRICA MAGIC VIEWERS' CHOICE AWARDS AMVCA gbé kalẹ̀. Ní ọdún 2019, ó jẹ́ ìkan lára àwọn tí ó ṣe adájọ́ fún GOLDEN MOVIE AWARDS AFRICA.
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Mulongo Wange (1997)
- Bamugamba (1998)
- Onkyaye (2000)
- Nkusibiddawo (2001)
- Kamuwaane (2002)
- Abakazi Twalaba (2003)
- Akulimbalimba (2004)
- Akalaboko (2007)[6]
- Maama (2007)
- Byonna Twala (2009)[7]
- Majangwa (2009)[8]
- Oly'omu (2012)
- Kiki Onvuma (2014)[9]
- Kibun'omu (2016)
Àmì ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Nominated work | Award | Category | Èsì |
---|---|---|---|---|
2013 | WHERE WE BELONG | Uganda Film Festival Award | Best Cinematography | Yàán |
2013 | WHERE WE BELONG | Uganda Film Festival Award | Best Sound | Yàán |
2017 | BA-AUNT | Pearl International Film Festival | Best TV Drama | Gbàá |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Actress "Dinah Akwenyi" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Indigenous Language Film | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Sound | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Screenplay "Mariam Ndagire" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Director "Mariam Ndagire" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Supporting Actor "Sebugenyi Rogers" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Young Actor "Nalumu Shamsa" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Young Actor "Dinah Akwenyi" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Feature Film | Yàán |
2018 | BA-AUNT | Zanzibar International Film Festival | Best TV Drama | Yàán |
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Serugo, Moses (28 February 2010). "Mariam Ndagire has more where that came from". The Observer (Uganda). Kampala. Archived from the original on 30 November 2020. Retrieved 4 February 2018.
- ↑ Rafsanjan Abbey Tatya (15 October 2010). "Mariam Ndagire to release new movie". Daily Monitor. Kampla. Archived from the original on 7 February 2019. Retrieved 4 February 2019.
- ↑ Abu-Baker Mulumba (26 July 2012). "Ndagire opens Tanuulu". The Observer (Uganda). Kampala. Archived from the original on 25 November 2018. Retrieved 4 February 2019.
- ↑ Stanley Gazemba (14 August 2014). "Mariam Ndagire Biography". Johannesburg: Musicinafrica.net. Retrieved 4 February 2019.
- ↑ Pat Robert Larubi (27 April 2018). "Strange But True, Mariam Ndagire Narrates Her Accidental Encounter With Music". Kampala: SoftPower Uganda. Retrieved 4 February 2019.
- ↑ Zacht BGentle (6 February 2007). "Akalaboko (Your Present)" (Music Video) (in Ganda). Retrieved 4 February 2019 – via YouTube.
- ↑ Paul Bill Migadde (8 October 2009). "Byonna Twala (Take Everything)" (Music Video) (in Ganda). Retrieved 4 February 2019 – via YouTube.
- ↑ Paul Bill Migadde (5 October 2009). "Majangwa" (Music Video) (in Ganda). Retrieved 4 February 2019 – via YouTube.
- ↑ Mariam Ndagire (10 March 2014). "Kiki Onvuma (Why Insult Me?)" (Music Video) (in Ganda). Retrieved 4 February 2019 – via YouTube.