Jump to content

Mariam al-Mahdi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mariam al-Mahdi
مريم الصادق المهدي
Foreign Minister of Sudan
In office
11 February 2021 – 22 November 2021
Alákóso ÀgbàAbdalla Hamdok
AsíwájúOmer Ismail (acting)
Arọ́pòAli al-Sadiq Ali
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1965 (ọmọ ọdún 59–60)
Omdurman, Sudan
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational Umma Party
BàbáSadiq al-Mahdi
Alma materUniversity of Jordan

Mariam al-Sadiq al-Mahdi (Lárúbáwá: مريم الصادق المهدي‎; tí a bí ní ọdún 1965) jẹ́ olóṣèlú ọmo orílẹ̀ èdè Sudan, adarí ẹgbẹ́ òṣèlú National Umma, àti mínísítà fún ètò àwọn orílẹ̀ ède láti ọjọ́ kọkànlá oṣù kejì ọdún 2021 títí di ìgbà tí ó kọ̀wé fiṣẹ́lẹ̀ ní ọjọ́ kejìlélógun ọdún kọkànlá 2021. Òun ni ọmọbìnrin Sadiq al-Mahdi, mínísítà àgbà tẹ́lẹ̀ rí fún orílẹ̀ ède Sudan.[1]

A bí al-Mahdi sí Omdurman ní ọdún 1965. Ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Umma, ó padà di adarí nínú ẹgbẹ́ òṣèlú náà.[1] Ó pa àmì ẹyẹ àkọ́kọ́ rẹ̀ nínú ìmọ̀ Dókítà òyìnbó ní Yunifásítì tí Jordan ní ọdún 1991, kí ó tó tẹ̀síwájú nínú ìmọ̀ Dókítà àwọn ọmọdé ní Liverpool School of Tropical Medicine ní ọdún 1995.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Mariam Al Mahdi: Revolutionary 'Kandake' as Sudan's Top Diplomat". eng.majalla.com.