Marie-Clémence Paes
Ìrísí
Marie-Clémence Paes | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Marie-Clémence Andriamonta 1959 (ọmọ ọdún 64–65) Madagascar |
Orílẹ̀-èdè | |
Iṣẹ́ | Director, producer, writer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1988–present |
Olólùfẹ́ | César Paes |
Marie-Clémence Andriamonta Paes (tí wọ́n bí ní ọdún 1959) jẹ́ olùdarí eré, olùgbéréjáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Fráǹsì àti Madagásíkà.[1] Ó ti ṣe àgbéjáde ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìrírí tó fi mọ́ Angano. . . Angano. . . , Mahaleo àti L'opéra du bout du monde.[2]