Martina Ohadugha
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Onyinyechi Martina Ohadugha | ||
Ọjọ́ ìbí | 5 Oṣù Kàrún 1991 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Ìga | 1.62m | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | Rivers Angels | ||
Number | 19 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Rivers Angels | |||
National team‡ | |||
2012– | Nigeria women's national football team | 35 | (2) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Martina Ohadugha jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5, óṣu May ni ọdun 1991. Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun River Angels[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Martina kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2012 ati 2014. Arabinrin naa kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 2015[4].