Jump to content

Mary Faber (Óniṣowo Ẹru)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Mary Faber Ni a tuma npe ni Mary Faber de Sanger, (a bini c. 1798 si Freetown, Guinea-Conakry– to si ku lẹyin ọdun 1857), jẹ oniṣowo ẹru ilẹ Afrika. Lati ọdun 1830s titi di ọdun 1852, arabinrin naa jẹ eniyan pataki ninu owo ẹru ṣise ti Atlantic lati ilẹ Guinea ati fun ija rẹ pẹlu Roya Navy ti ilẹ British;Awọn ajọ yi jẹ Squadron to lo di owo ẹru ṣise[1].

Mary Faber ni a bini ilẹ Freetown fun awọn ara Nova Scotian[2]. Ni ọdun 1816, Mary fẹ ọlọkọ oju omi ilẹ Arika Paul Faber (d. 1851) to da owo oko ẹrun fun ra rẹ ni ọdun 1809 ni agbegbe Conakry[3]. Ọkọ rẹ̀ da ibudo oko owo silẹ si Sangha ni odo Rio Pongp ni ibi ti awọn tọkọ taya ti di ilẹ iṣẹ ẹru silẹ. Eyi jẹ oko ẹru ti o lagbara latara awọn óniṣowo oko ẹru yoku to ni ẹru ni agbegbe naa.

Ọkọ Mary lo dari ọkọ oju omi ẹru to maa nlọ si ilẹ Cuba ṣugbon Mary Faber ṣiṣẹ lori awọn oko owo to wa ni Rio Pongo. Mary ni awọn ẹru bi ẹgbẹrun lọna mẹfa to jẹ bi nkan ini fun ni ọdun 1827.

Lati ṣọra fun ija awon squadron Royal Navy to lodi si oko ẹru eyi to maa jagun si ibudo oko ẹru. Lẹyin ti wọn ti fagile oko ẹru ti ilẹ british, Mary bẹ̀rẹ sini lo awọn ẹru rẹ fun óṣiṣẹ abẹ ile lẹyin to sọ ibudo oko ẹru rẹ di oko. Mary Faber ni awọn ọmọ ogun rẹ to maa nlo nigba ija. Larin ọdun 1838-1840, Mary kogun ba óniṣowo ẹru to jẹ orogun rẹ William Ormond ni Bangalan.

Ni ọdun 1842,Mary Faber ati akẹgbẹ rẹ Bailey Gomez Lightburn da ọmọ ogun wọn papọ lati ṣè iranlowo fun awọn ọrẹ wọn, Fula lati kogun ba Susu, Thia ninu ija ade lati fi eyan ti wọn sibẹ eyi lo jẹ nkan pataki fun Fula, Faber ati Lightburn[4].

Ọdun 1840 jẹ igba pataki fun oko owo ni agbegbe naa, eyi lo mu ki Faber ni oko ẹ̀pa ati Coffee ṣugbọn ó ṣi bẹrẹ̀ oko ẹ̀ru ni a bẹlẹ̀[5].

Ni ọdun 1852, Mary Faber fi iṣẹ rè le ọmọkunrin rẹ William Faber to bẹrẹ owo oko ẹru titi di ọdun 1860[6]. Awọn missionary darukọ Mary Faber sẹyin ni ọdun 1857 ni ipa rẹ̀ gẹgẹbi mama ilẹ rẹ ati iya William Faber.

  1. Aidoo, Theodora (2019-09-09). "5 little-known black female slave traders who changed the course of history - Page 6 of 6". Face2Face Africa. Retrieved 2023-08-26. 
  2. "The Rise and Fall of Mary Faber, West Africa’s Notorious Slave Trader in the Early 19th Century". Flipboard. 2023-01-24. Retrieved 2023-08-26. 
  3. Thomas, H. (1997). The Slave Trade: The Story of the Atlantic Slave Trade: 1440 - 1870. A Touchstone Book. Simon & Schuster. p. 684. ISBN 978-0-684-83565-5. https://books.google.com.ng/books?id=lmPFnzXU7o0C&pg=PA684. Retrieved 2023-08-26. 
  4. Montgomery, Warner M. (2004-11-19). "Adventure Travel". Columbia Star - Columbia's locally owned weekly newspaper since 1963. Retrieved 2023-08-26. 
  5. Havik, P.J. (2004). Silences and Soundbites: The Gendered Dynamics of Trade and Brokerage in the Pre-colonial Guinea Bissau Region. Modernity and belonging. Lit. p. 249. ISBN 978-3-8258-7709-5. https://books.google.com.ng/books?id=ymkdf-PIYGoC&pg=PA249. Retrieved 2023-08-26. 
  6. "Slave Trade Expedition to Africa". Columbia Star - Columbia's locally owned weekly newspaper since 1963. 2006-08-25. Retrieved 2023-08-26.