Mary Twala

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mary Twala-Mhlongo
Ọjọ́ìbíMary Kuksie Twala
(1939-09-14)14 Oṣù Kẹ̀sán 1939
Soweto, Johannesburg, Union of South Africa
Aláìsí4 July 2020(2020-07-04) (ọmọ ọdún 80)[1]
Parklane Private Hospital, Johannesburg, South Africa
Orílẹ̀-èdèSouth African
Orúkọ mírànMampinga
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1960s – 2020
Notable workHlala Kwabafileyo, Molo Fish, Ubizo: The Calling, Yizo-Yizo
Olólùfẹ́Ndaba Mhlongo (deceased)
Ẹbí
  • Somizi Mhlongo (son)
  • Archie Mhlongo (son, deceased)
  • Bahumi Madisakwane (granddaughter)

Mary Kuksie Twala (bíi ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1939)[2] jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ní ọdún 2011, wan yàn kalẹ̀ fún ẹ̀bùn Best Actress in a Supporting Role lati ọdọ Africa Movie Academy Award .

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Twala tí kópa nínú orísìírísìí eré ìbílẹ̀ ni South Áfríkà. Ó kópa nínú eré Hopeville gẹ́gẹ́ bíi Ma Dolly, èyí sì jẹ kí wọn pé fún ẹ̀bùn Best Supporting Actress láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Academy Awards.

Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀

  • Life, Above All
  • Beat the Drum
  • Leading Lady
  • Ghost Son
  • Mapantsula (1988)
  • Sarafina! (1992)
  • Hopeville[3]
  • State of Violence (2010)
  • Black Is King (2020)
  • Yızoyızo
  • Ubizo: The Calling.[4]
  • Comatose[5]
  • Vaya[6]
  • Beyond the River.[7][8]

Ikú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Mary Twala kú ní ọjọ́ kẹrin oṣù keje, ọdún 2020 ni ago mọ́kànlá ni ilẹ̀ ìwòsàn àdáni tí Parklane private hospital ni ìlú Johannesburg.[9] Wọ́n sín ni ọjọ́ kẹsàn-án oṣù keje, ọdún 2020 ni ìlú Soweto.

Awọn Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Nyathi, Ayanda. "Legendary SA actress Mary Twala dies at 80". ewn.co.za. Archived from the original on 2020-07-07. Retrieved 2020-10-12. 
  2. "Ms Mary Twala Mhlongo". thepresidency. Archived from the original on 10 December 2019. Retrieved 15 April 2020. 
  3. Stead, Andy. "Global acclaim for Hopeville". gautengfilm.org.za. Archived from the original on 15 September 2018. Retrieved 4 July 2020. 
  4. "Mary Twala profile". tvsa.co.za. Retrieved 4 July 2020. 
  5. Izuzu. "Fabian Adeoye Lojede, Bimbo Akintola, Hakeem Kae Kazim star in new movie". Pulse. Retrieved 4 July 2020. 
  6. Kyle, Zeeman. "Mary Twala to make her big screen return". channel24.co.za. Retrieved 4 July 2020. 
  7. Avantika, Seeth. "Suspense, drama and comedy jam-packed into an amazing local production". channel24.co.za. Retrieved 4 July 2020. 
  8. "Local movie premiere draws hundreds". Channel 24. Retrieved 4 July 2020. 
  9. "BREAKING: Veteran actress Mary Twala passes away". MzansiNewsLive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-04. Retrieved 2020-07-04.