Jump to content

Mary Uduma

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mary Uduma
Ọjọ́ìbíMay 25, 1952
Orílẹ̀-èdèNigerian
OrganizationNigeria Internet Registration Association

Mary Uduma (bíi ni ọjọ́ meedogbon oṣù karùn-ún ọdún 1952)[1] jẹ́ olùdarí ni ẹ méjì fún Nigeria Internet Registration Association (NIRA).[2][3] Òun ni alága fún Nigeria Internet Governance Forum.[4][5]

Udoma gboyè nínú ẹ̀kọ́ Accounting lati ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Institute of Management Technology àti University of Lagos.[1]

Uduma sì ṣé pelu Federal Audit ni ìgbà tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos. Ó padà wá si ṣé pelu Ivory Merchant Bank. Ní ọdún 1995, ó darapọ̀ mọ́ Nigerian Communications Commission gẹ́gẹ́ ìgbà kejì adarí owó. Ní ọdún 1999, ó di ìgbà kejì adarí ni ẹ̀kà tí Tariff and Charges. Wọn gbé lọ sí Corporate planning ni ọdún 2005, ó sì ṣíṣe nibe fún ọdún kan kí ó tó di adarí fún Licensing. Ó di olórí fún ẹ̀ka Consumers affairs ni odun 2011.[1] Uduma tí ṣe ìgbà kejì olùdarí fún Nigeria Internet Registration Association kí ó tó wà di olùdarí kejì fun ẹgbẹ́ náà. Ó ṣe olùdarí ni ẹ méjì fún ẹgbẹ́ náà.[6] Òun ni alága fún Nigeria Internet Governance Forum.[7][8] Ó ṣe aṣojú fún NIGF ni ọdún 2019 ni ayẹyẹ ọjọ́ tí wọn yà kalẹ fún àwọn obìnrin ni gbogbo agbaye tí wọn ṣe ni Abuja.[9]

Ní ọdún 2016, ó gbà ẹ̀bùn láti ọdọ NIRA Presidential Award.[10][11]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 "The Communicator Online - The Communicator Online". www.ncc.gov.ng. Retrieved 2020-05-08. 
  2. "NiRA BOD - Nigeria internet Registration Association (NiRA)". www.nira.org.ng. Archived from the original on 2020-08-05. Retrieved 2020-05-08. 
  3. "There is money in domain name business, NIRA Boss". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2010-09-07. Retrieved 2020-05-08. 
  4. "#InternationalWomensDay: Working on digital inclusion for women —NIGF". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-08. Retrieved 2020-05-08. 
  5. "Nigeria's internet users reaches 103m - NCC - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-05-08. 
  6. "NiRA Decries Govts, MDAs Hosting .ng Servers Abroad". Daily Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-03-16. Retrieved 2020-05-08. 
  7. "ICT expert urges government to build more ICT hubs". Archived from the original on 2023-09-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "NIGF to focus on enabling digital commonwealth for growth". Archived from the original on 2023-09-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. "IGF seeks women participation in internet governance for development". Archived from the original on 2023-09-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. "Mary Uduma, CFA, Wunmi Hassan Receive NiRA Presidential Awards 2016". CFAmedia.ng - Startups | Media | Business | Technology News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-04. Retrieved 2020-05-08. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  11. "Mary Uduma, others awarded at 2016 NiRA awards ceremony". TechCity (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-04. Retrieved 2020-05-08.