Jump to content

Matapa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Matapa jẹ́ oúnjẹ Mozambic, tí a sè pẹ̀lú ewé ẹ̀gẹ́ kékeré,[1] èyí tí ó sábàá máa ń jẹ́ lílọ̀ nínú ìyá odó onípákó ńlá àti ọmọ odó síwájú kí ó tó di ṣíṣè pẹ̀lú gálìkì, àlùbọ́sà àti mílíìkì àgbọn.[1] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ matapa ni ó ní cashew nuts, èdè,[2] tàbí shrimp.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 Oberholzer, Sanet (2023-11-30). "RECIPE | Matapa and prawns to get you in the mood for the holidays". TimesLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-02-21. 
  2. Odusanya, Yemisi (2018-07-14). "6 delicacies you must try in Mozambique". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-02-21.