Matsuo Bashō

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Láàrin orúkọ ará Japan yìí, orúkọ ìdílé ni Matsuo.
Matsuo Bashō (松尾 芭蕉)
Pen nameSōbō (宗房)
Tōsē (桃青)
Bashō (芭蕉)
Iṣẹ́Poet
Ọmọ orílẹ̀-èdèJapanese
Notable worksOku no Hosomichi

Àdàkọ:Contains Japanese text Matsuo Bashō (松尾 芭蕉?, 1644 – November 28, 1694), abiso Matsuo Kinsaku (松尾 金作?), nigbana bi Matsuo Chūemon Munafusa (松尾 忠右衛門 宗房?)[1][2], je akoewi togbajumojulo ni igba Edo ni Japan. Nigba aye re, Bashō gbajumo fun awon ise re ninu iru collaborative haikai no renga alajobarasepo; loni, leyin opo orundun awiso lori ise re, o gbajumo bi oga ninu haiku soki ati kedere. Awon ewi re gbajumo kakiri aye.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "松尾芭蕉". The Asahi Shimbun Company. Retrieved 2010-11-22. Àdàkọ:Ja icon
  2. "芭蕉と伊賀上野". 芭蕉と伊賀 Igaueno Cable Television. Retrieved 2010-11-22. Àdàkọ:Ja icon