Matthew Nwogu
Ìrísí
Matthew Nwogu | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria from Imo | |
Right Honorable | |
Constituency | Aboh Mbaise/Ngor Okpala Federal Constituency |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga June 2023 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 24 December 1960 |
Occupation | Politician, lawyer |
Matthew Nwogu je olóṣèlú ọmọ orile-ede Nàìjíríà to n soju àgbègbè Aboh Mbaise/Ngor okpala ni ile ìgbìmọ̀ aṣòfin ipinle Imo . [1]
Ìrìnàjò òṣèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ọdun 2024 wọn dibo yan gẹgẹbi aṣofin àgbà labẹ ẹgbẹ òṣèlú Labour Party gẹgẹbi asoju Aboh Mbaise/Ngor Okpala ni ilé ìgbìmò aṣòfin àgbà ní ìlú Abuja, tí òsì fí ìdí akegbe rẹ tí ń ṣe Akwitti Ifeanyi tí inú ẹgbẹ òṣèlú All Progressives Congress àti Mr. Agulanna Albert Chibuzor ọmọ ẹgbẹ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP).[2]