Mavis Ogun
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 24 Oṣù Kẹjọ 1973 | ||
Playing position | Defender | ||
National team‡ | |||
Nigeria women's national football team | |||
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 19 June 1999 (before the 1999 FIFA Women's World Cup) |
Mavis Ogun jẹ́ ọ̀kan lára agbábọ́ọ̀lù obìnrin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógun, oṣù kẹjọ ọdún 1973. Arábìnrin náà jẹ́ agbábọ̀ọ̀lú ọlọ́wọ́ ẹ̀yìn fún ikọ̀ Nàìjíríà lobínrin [1][2]. Ó wà lára àwọn agbábọ̀ọ̀lù tó kópa nínu ife ẹ̀yẹ àgbáyé obìnrin ti FIFA ní ọdún 1991, 1995 àti ọdún 1999.
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Mavis ti kópa nínu Cup FIFA àwọn obinrin àgbáyé ní ọdún 1991, 1995 àti 1999[3].