Maya Angelou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Maya Angelou
Ìbí Marguerite Ann Johnson
Oṣù Kẹrin 4, 1928(1928-04-04)
St. Louis, Missouri, U.S.
Aláìsí Oṣù Kàrún 28, 2014 (ọmọ ọdún 86)
Occupation Poet, civil rights activist, dancer, film producer, television producer, playwright, film director, author, actress, professor
Ethnicity African American
Literary movement Civil rights

mayaangelou.com

Maya Angelou (play /ˈm.ə ˈænəl/;[1] abiso Marguerite Ann Johnson; April 4, 1928 – May 28, 2014)[2] je olukowe ati akoewi ara Amerika. O gbajumo fun awon iwe ikoigbesiayearaeni mefa to ko ti won da lori igba ewe ati igba odo re.[3] Akoko ninu won ni, I Know Why the Caged Bird Sings (1969), eyi da lori gba re titi de omo odun metadinlogun. O je ko gbajjumo kakiriaye, o si je didaloruko fun Ebun Iwe Orile-ede Amerika. O ti gba iwe eri eye bi 30 be sini o je didaloruko fun Ebun Pulitzer fun iwe ewi 1971 re, Just Give Me a Cool Drink of Water 'Fore I Diiie.[4]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe
  2. Àṣìṣe
  3. Àṣìṣe
  4. Àṣìṣe