Jump to content

Mazahir Uloom Jadeed

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use Indian English

Mazahir Uloom Jadeed
Mazahir Uloom Jadeed.jpg
Mazahir Uloom Jadeed
Established1983; ọdún 41 sẹ́yìn (1983)
TypeIslamic seminary
Parent institutionMazahir Uloom (pínyà lọ́dún 1983)
RectorMuhammad Aaqil Saharanpuri
LocationSaharanpur, Uttar Pradesh, India
NicknameMazahir

Ọ̀gbẹ́ni Mazahir Uloom Jadeed jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀sìn Mùsùlùmí ní Saharanpur, lórílẹ̀-èdè India, ó yapa láti ara ilé-ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀sìn Mùsùlùmí Mazahir Uloom, tí ó sì dá dúró lọ́dún. Ó máa ń ṣe àtẹ̀jáde ìwé jọ́nà kan tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Mazāhir-e-Uloom.[1] Títí di oṣù kẹta ọdún 2022, Muhammad Aaqil Saharanpuri ni Gíwá àti Ọ̀jọ̀gbọ́n àgbà ti ẹ̀kọ́ imọ hadith ti ilé-ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀sìn Mùsùlùmí náà.[2]

Àdàkọ:More Ilé-ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀sìn Mùsùlùmí náà yan Abdul Azīz gẹ́gẹ́ bí Gíwá rẹ̀ àkọ́kọ́ lọ́dún 1986 sí 1991.[3] Salman Mazahiri served on the administration from 1996 to 20 July 2020.[4]

A closer view of the seminary

Ilé-ẹ̀kọ́ náà ṣẹ̀dá ipò "Ameen-e-Aam" (Akọ̀wé Àgbà) lọ́dún 1988, tí wọ́n sì yan Muhammad Talha Kandhlawi gẹ́gẹ́ bí Akọ̀wé Àgbà àkọ́kọ́ tí ó sì wà lórí ipò náà títí di ọdún 1993.[5]

Àwọn tí jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ náà àti Ẹẹ̀ka-ẹ̀kọ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]