Melanésíà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Melanesia)
Melanesia je omo agbegbe Oseania to fe lati apaiwoorun opin Okun Pasifiki titi de Okun Arafura, ati tokoju si ilaorun si Fiji. Agbegbe kopo opo awon erekusu to wa ni ariwa ati ariwailaorun Ostrelia. Oruko Melanesia (lati Greek: μέλας, dudu; νῆσος, erekusu) koko je lilo latowo Jules Dumont d'Urville ni 1832 lati setokasi awon eya eniyan ati idipo jeografi awon erekusu to yato si Polynesia ati Maikronesia.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |