Mellissa Akullu
Ìrísí
No. 15[1] – Vanguard | |
---|---|
Forward | |
Personal information | |
Born | 25 August 1999 |
Nationality | Ugandan |
Listed height | 6 ft 1 in (1.85 m) |
Career information | |
College | |
Career highlights and awards | |
Mellissa Akullu (tí wọ́n bí ní 25 August 1999) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti ilẹ̀ Uganda. Ó kópa nínú ìdíje ti 2023 basketball season, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n tó dára jù lọ.[4]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Melissa ní ìlú Kampala, Uganda.
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní oṣù kejì ọdún 2024, Golden State Athletic Conference pe Melissa ní agbábọ́ọ̀lù tó dára jù lọ ní ọ̀sẹ̀ náà (GSAC), níbi tí ó ti gba pọ́ìntì 23.5 àti àtúnṣe 19.0 fún ìjáwé olúborí ní Vanguard.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ University, Vanguard (2024-02-28). "Akullu, Davis Earn Marquee Women’s Basketball Honors". Vanguard University. Retrieved 2024-03-19.
- ↑ "Gazelles center Akullu named GSAC Player of the Year". MTN Sports. 2024-02-28. Retrieved 2024-03-19.
- ↑ "Student Spotlight: Melissa Akullu '24". Vanguard University. 2023-04-17. Retrieved 2024-03-19.
- ↑ "Melissa Akullu gets NAIA All-American nod". Bukedde. 2023-03-27. Retrieved 2024-03-19.
- ↑ "Melissa Akullu (2/12/2024)". Golden State Athletic Conference. 2022-10-17. Retrieved 2024-03-19.