Jump to content

Vanguard

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Vanguard jẹ ìwé iroyin ojoojumọ ti Vanguard Media ma ún gbejade, Vanguard media kalè sí ìpínlè Èkó, Nàìjíríà.  Oniroyin Sam Amuka-Pemu pèlú àwon òré rè méta lódá Vanguard Media silẹ ni ọdun 1984. [1] Vanguard media tún ma ún gbé ìwé iroyin ojojumo náà sí orí ayelujara fún àwon ènìyàn lati káà níbè. [2] Iwe irohin naa jẹ ọkan ninu awọn diẹ ni Naijiria tí wón kà sì pé kó sí lábé iṣakoso oloselu, awọn iwe-iroyin miràn bí èyí ni The Punch, The Sun ati The Guardian.  Ni Oṣu Karun ọdun 1990, Col. Raji Rasaki, Gomina Ologun ti Ìpínlè Eko da iwe-iroyin naa duro fún ìgbà díè.

Ni Oṣu Kéjìlá ọdun 2008, ìwé iroyin Pointblanknews.com tí ó kalè sí Amerika ṣe atẹjade kan ti o fi ẹsun kan iyawo olutẹwe Vanguard Newspapers pé opaniyan setutu. Vanguard gbe oniroyin naa lo si kootu, won ni pé eni tí oso òrò náà ún gbíyanju láti fi gba owo lowo won ni. [3]

  1. "Sam Amuka Biography". MassMediaNG. 2020-02-26. Archived from the original on 2022-08-15. Retrieved 2022-04-29. 
  2. "E-editions". Vanguard News. 2015-11-17. Retrieved 2022-04-29. 
  3. "Africans In America News Watch". africansinamericanewswatch.com. 2009-06-15. Archived from the original on 2009-06-15. Retrieved 2022-04-29.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)