The Guardian

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
The Guardian
Guardian logo.png
Type Ìwé ìròyìn olójoojúmọ́
Publisher Guardian Newspapers Limited
Founded Ọdún 1983
Headquarters Ìlú Èkó
Official website http://www.guardian.ng/

The Guardian jẹ́ Ìwé ìròyìn olójoojúmọ́ tí àtẹ̀jáde rẹ̀ ń wáyé ní Ìlú Èkó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ilé iṣẹ́ Guardian Newspapers Limited ni ó ń ṣakápò rẹ̀.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]