Memuna Darku
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kẹtàdínlógún osù Kẹrin ọdún 1979 | ||
Playing position | Agbedeméjì | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ghatel Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana | 3 | (0) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Memuna Darku tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún osù Kẹrin ọdún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti àwọn obìnrin ará ilẹ̀ Ghana kan tí ó ń ṣeré gẹ́gẹ́ bíi agbedeméjì . Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orìlẹ̀-ède Ghana . Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó kópa ní bi FIFA Women's World Cup ní ọdún 2007 . Lórí ìpele ẹgbẹ́, ó ṣeré fún Ghatel Ladies ní Ghana. [1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World CupÀdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World CupÀdàkọ:Authority control