Mercy Abang
Mercy Bank Abang jẹ́ oniroyin ni Nàìjíríà.[1] Ò gbà ẹ̀bùn nínú ìròyìn ni ọdún 2017 láti ọ̀dọ̀ Hammarskjold Awards ni United Nations.[2] Ò má ń ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ tí ó pè àkọlé rẹ̀ ni ọ̀rọ̀ pẹ̀lú Abang Mercy, ó sì ti gbà àwọn àlejò bíi Rẹno Omokri, Dele Momodu àti Chude Jideonwo.[3] Ní ọdún 2017, ó gbà ẹ̀bùn Woman of the year ni èka ìròyìn.[4] Ní ọdún 2012, ó wá láàrin àwọn obìnrin ọ̀dọ́ mẹ́wàá tí wọn ní ọjọ́ ọ̀la dídára.[5] Ò ṣe onìròyìn nígbà ìdìbò orílẹ̀ èdè Ghana ni 2017.[6] Ó kọ oríṣiríṣi ìròyìn nípa àwọn ìkan tí àwọn olùsọ àgùntàn tí Fulani ń ṣe àti bíi wọn ṣe pa àwọn èèyàn ní àgbègbè Gbagyi.[7] O bẹ́ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ lórí telefisionu gẹ́gẹ́ bíi onìròyìn òṣèlú pelu Independent Television and Radio ni Abuja. Ó ti si ṣé pelu àwọn ilé iṣẹ́ bíi Oxfam GB Nigeria, West African Civil Society Forum, HeinrichBoell Foundation,EcoJournalism ati YNaija.[8][9] Ní ìgbà tí ó wà ní HeinrichBoell Foundation, ó kọ àwọn ìròyìn nípa bí àgbègbè àyíká àwọn ìlú ni Nàìjíríà ṣe rí àti bí wọn ṣe má rí ní ọjọ́ ọ̀la.[10][11][12][13][14][15][16][17][18] Ní ọdún 2014, wọn pé sì ọ̀rọ̀ lórí ìjọba, ẹ̀tọ́ ènìyàn àti ìjọba tiwa ń tiwa èyí tí African Union gbé kalẹ̀ tí àwọn èèyàn láti orílẹ̀-èdè èdè tí ó kọjá ogójì sì wá níbè.[19][20] Ní oṣù kẹta ọdún 2015, òun àti Kadaria Ahmed tí ó jẹ́ oniroyin fún BBC, jọ ṣe atọkun ètò ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ lórí telefisionu fún Attahiru Jega tí ó jé alága fún INEC.[21] Ó ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ ni oṣù kẹsàn-án ọdún 2014 fún ìgbà kejì adarí tẹ́lẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Atiku Abubakar. Mercy jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ "Enough is Enough" tí Chude Jideonwo gbé kalẹ̀.[22][23] Ó pèsè iranlọwọ fún ètò LightupNigeria èyí tí Amara Nwankpa gbé kalẹ̀ láti rán àwọn tí wọn ṣe àìsàn lára bíi wọn ṣé ń se wúrà ni Zamfara.[24]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Spark, The (2017-10-09). "Meet Mercy - The Freelance Journalist". The Spark (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 25 February 2020. Retrieved 2020-05-07.
- ↑ "Nigerian Journalist, Abang, 3 Others Win Dag Hammarskjöld Award". https://www.pmnewsnigeria.com/2017/09/14/nigerian-journalist-abang-3-others-win-dag-hammarskjold-award/.
- ↑ "CONVERSATIONS WITH MERCY ABANG: "I AM AN ENTREPRENEUR, NOT AN ACTIVIST" – CHUDE JIDEONWO BARES IT ALL". https://ynaija.com/conversations-with-abang-mercy-i-am-an-entrepreneur-not-an-activist-chude-jideonwo-bares-it-all/.
- ↑ "Nominees for Her Network Woman of the Year Awards 2017 revealed". Archived from the original on 4 August 2020. https://web.archive.org/web/20200804150808/https://guardian.ng/guardian-woman/nominees-for-her-network-woman-of-the-year-awards-2017-revealed/.
- ↑ "Who Runs The World: 10 Young Nigerian Women to Watch (Part II) « Belinda Otas". Belindaotas.com. 6 June 2012. Archived from the original on 2 November 2013. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 12 February 2017. Retrieved 12 April 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Mercy Abang (30 January 2017). "Mercy Abang: The Untold Stories of the Killing of Farmers in Niger State". BellaNaija.com. Retrieved 27 July 2017.
- ↑ "Mercy Abang: It is cool to be called an activist, but not cool to join a political party? Give me a break". YNaija. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "Government dams not responsible for floods – Minister". Ecojournalism.org. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "Green Deal Nigeria – Alternativen zum Öl | Heinrich Böll Stiftung" (in Èdè Jámánì). Boell.de. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "'Nigeria's total dependence on oil suicidal' – Vanguard News". Vanguardngr.com. 15 July 2013. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "Internalising the Green debate for a post oil economy". ecojournalism.org. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "Internalising the Green debate for a post oil economy ~ by @AbangMercy". Omojuwa. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "Green Deal Nigeria" (PDF). Boell.org. Archived from the original (PDF) on 2 November 2013. Retrieved 31 October 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Group advocates for a national Green Agenda – Premium Times Nigeria". Premium Times. 2 November 2012. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "Add an article". London 21. Archived from the original on 2 November 2013. Retrieved 31 October 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Green Deal Nigeria Tickets, London – Eventbrite". Greendealnigeria.eventbrite.com. 10 November 2012. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "Jean Lambert Green MEP for London". Jeanlambertmep.org.uk. 10 November 2012. Archived from the original on 2 November 2013. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ "The 2nd Annual Youth Consultation On Democracy, Human Rights And Governance In Africa #DGTrends". NewsWireNGR.com. Retrieved 27 July 2017.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 1 October 2014. Retrieved 12 April 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ TechHerNG (7 December 2016). "Mercy Abang: Multi tasking is not a big deal!". TECHHER (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 January 2020.
- ↑ "Mercy Abang | Think Africa Press". 72.27.231.67. Archived from the original on 26 August 2013. Retrieved 31 October 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Press Release->Enough Is Enough". Omoyeni-disu.blogspot.com. 11 January 2011. Retrieved 31 October 2013.
- ↑ Oladipo, Tomi (12 April 2013). "BBC News – Cleaning up Nigeria's toxic playgrounds". Bbc.co.uk. Retrieved 31 October 2013.