Mercy Airo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mercy Airo
Personal information
OrúkọMercy Akinyi Airo
Ọjọ́ ìbí20 Oṣù Kẹ̀wá 1999 (1999-10-20) (ọmọ ọdún 24)
Ibi ọjọ́ibíKisumu, Kenya
Playing positionforward
Club information
Current clubKisumu All Stars F.C.
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Kisumu All Stars F.C.
National team
20
Kenya women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Mercy Airo jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 20, óṣu october ni ọdun 1999. Agbabọọlu naa ṣere fun Kisumu All Starlets FC gẹgẹbi forward[1][2][3].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Mercy kopa ninu ere idije awọn obinrin CECAFA ati Cup awọn obinrin ilẹ turkey to waye ni ọdun 2020[4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.flashscore.com.ng/player/airo-mercy/6ZZJJzV8/
  2. https://allafrica.com/stories/201711030155.html
  3. https://gibosports.com/update/airo-aquino-keeps-gaspo-flying-in-wpl/1039304[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-07-26. Retrieved 2022-06-13.