Mercy Ebosele

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mercy Ebosele
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Keje 1984 (1984-07-25) (ọmọ ọdún 39)
Ipinle Oyo,Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́òṣèrébìnrin
Olólùfẹ́Kehinde Olasupo[1]

Mercy Ebosele jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3]

Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Mercy Ebosele si Ipinle Oyo.[4] Mercy jẹ́ ikẹ̀fà ninu ọmọ méjé tí àwọn òbí rẹ̀ bí.Ò lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Memorial Primary School ní ìlú Oyo.Ó lo si ile-eko girama ti Oba Adeyemi Secondary School nilu Oyo bakan na.Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ eré ori-itage ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti Ibadan.[5]

Ìgbésí ayé ara ẹni[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni odún 2017,Mercy fé Kehinde Olasupo ti inagije re n jé Kenny Keyz ti won si jo n gbe layo.[1][6][7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Actress Mercy Ebosele: Biography And Net Worth". Ken Information Blog. January 22, 2020. Retrieved May 24, 2022. 
  2. "Yoruba Actress, Mercy Ebosele Releases Stunning Photos". Nigeriafilms.com. Retrieved May 24, 2022. 
  3. AjoseMercy-Ajoke-Ebosele, Kehinde (June 6, 2015). "Actresses in the Yoruba movie industry are not promiscuous - Mercy Ajoke Ebosele". Vanguard News. Retrieved May 24, 2022. 
  4. "Actor, Mercy Ebosele Is A Dazzling Birthday Princess At 40". MusicNolly. July 25, 2020. Retrieved May 24, 2022. 
  5. "My stature was a challenge when I started acting —Mercy Ebosele - Punch Newspapers". Punch Newspapers. September 3, 2017. Retrieved May 24, 2022. 
  6. Amodeni, Adunni (August 1, 2017). "Yoruba actress Mercy Ebosele stuns as she ties the knot with her heartthrob (photos)". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved May 24, 2022. 
  7. "Events that shaped Nollywood in 2017". The Sun Nigeria. January 6, 2018. Retrieved May 24, 2022.