Jump to content

Mia And The White Lion

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use South African English

Mia and the White Lion
Fáìlì:Mia and the White Lion Official U.S. Poster.jpg
American release poster
AdaríGilles de Maistre
Olùgbékalẹ̀
  • Valentine Perrin
  • Jacques Perrin
  • Nicolas Elghozi
  • Gilles de Maistre
  • Stephane Simon
  • Catherine Caborde
Òǹkọ̀wé
Àwọn òṣèré
OrinArmand Amar
Ìyàwòrán sinimáBrendan Barnes
OlóòtúJulien Rey
OlùpínStudioCanal (France)
Déètì àgbéjáde
  • 26 Oṣù Kejìlá 2018 (2018-12-26) (France)
  • 1 Oṣù Kejì 2019 (2019-02-01) (Germany)
  • 12 Oṣù Kẹrin 2019 (2019-04-12) (United States)
Àkókò98 minutes
Orílẹ̀-èdè
  • France
  • Germany
  • South Africa
Èdè
  • English
  • French
ÌnáwóÀdàkọ:Euro[1]
Owó àrígbàwọlé$36.4 million[2][3]

Mia and the White Lion (Faransé: Mia et le lion blanc)[4] jé fíìmù odún 2018 eléyìí tó wà fún àwon omodé,ebí àti ìrìnàjò ti Gilles de Maistre jé Olùdarí rè. Àwon olùkópa gbajúgbajà inú fíìmù naa ni [Daniah de Villiers], [Mélanie Laurent] àti Langley Kirkwood. Fíìmù náà jáde ni ojó kerìndínlógbòn odún 2018 ni ilè Faransé [France][5][6] àti ní orílè èdè Amérícà [United States] ni osù keta, ojó kejìlá, odún 2019.[7]

  1. "Mia et le lion blanc (Mia and the White Lion) (2018) - JPBox-Office". JPBox-Office. Retrieved 11 September 2019. 
  2. "Mia and the White Lion (2019)". Box Office Mojo. Retrieved 29 May 2019. 
  3. "Mia and the White Lion (2019)". The Numbers. Retrieved 2 August 2019. 
  4. Mia and the White Lion | Movie Site & Trailer | April 12, 2019, archived from the original on 12 April 2019, retrieved 2019-04-05 
  5. "Anecdotes du film Mia et le Lion Blanc" (in Èdè Faransé). AlloCiné. Retrieved January 12, 2019. 
  6. "Mia et le lion blanc: Les scènes où Mia joue avec le félin adulte sont à couper le souffle" (in fr). Première. December 26, 2018. http://www.premiere.fr/Cinema/News-Cinema/Mia-et-le-lion-blanc-Les-scenes-ou-Mia-joue-avec-le-felin-adulte-sont-a-couper-le-souffle--critique. 
  7. McNary, Dave (2019-02-06). "Film News Roundup: Family Adventure 'Mia and the White Lion' Set for U.S. Release". Variety (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-02-06.