Michael Clarke Duncan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Michael Clarke Duncan (2009)

Michael Clarke Duncan (December 10, 1957 – September 3, 2012) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ókó nínú eré The Green Mile (1999) tí wọ́n sì fa orúkọ rẹ̀ sílẹ fún àmì ẹ̀yẹ Akádẹ́mì.[1]. Ní ọdún 2009, ó jọ̀wọ́ ẹran jíjẹ tí ó sì jádé fún ìpolongo PETA, tí ó ń jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ̀ ìlera tí ó rọ̀ mọ́ ewé jíjẹ.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]