Michael Kearney

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Michael Kearney Òun ni ó kéré jù láti gba oyè ní Yunifásítì. Ọmọ ọdún mẹ́fà àti oṣù méje ni ó jẹ́ nígbà tí ó wọ santa Rosa Junior College, California ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà ní 1990. Ní ọdún 1994 ni ó gba oyè B.A. nínú Anthropology ní. University of South Alabama ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà nígbà tí ó jẹ ọmọ ọdún mẹ́wàá àti oṣù mẹ́rin.