Micheline Calmy-Rey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Micheline Calmy-Rey
Member of the Swiss Federal Council
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 January 2003
AsíwájúRuth Dreifuss
President of Switzerland
In office
1 January 2007 – 31 December 2007
Vice PresidentPascal Couchepin
AsíwájúMoritz Leuenberger
Arọ́pòPascal Couchepin
Head of the Federal Department of Foreign Affairs
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 January 2003
AsíwájúJoseph Deiss
Vice President of Switzerland
In office
1 January 2006 – 31 December 2006
ÀàrẹMoritz Leuenberger
AsíwájúMoritz Leuenberger
Arọ́pòPascal Couchepin
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Keje 1945 (1945-07-08) (ọmọ ọdún 78)
Sion
Àwọn ọmọ2
ResidenceGeneva
{{{blank1}}}André Calmy

Micheline Anne-Marie Calmy-Rey (ojoibi 8 July 1945) je oloselu ara Switzerland to di olori fun Eka Ijoba Apapo fun Oro Okere — eyun, alakoso oro okere orile-ede Switzerland. O tun je ikan ninu Igbimo Ijoba Apapo Switzerland lati 2002, ati Aare ni 2007.

Igba ewe ati ikeko[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Calmy-Rey je bibi ni Sion ni ibile Valais fun Charles ati Adeline Rey. Calmy-Rey gba iwe eri ni 1963 ni St. Maurice, ati iwe eri DEA ninu sayensi oloselu ni Institut de hautes études internationales (HEI) (Graduate Institute of International Studies) ni 1968. O wole oko ni 1966 ni gba to fe André Calmy. Won ni omo meji.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]