Micheline Calmy-Rey
Ìrísí
Micheline Calmy-Rey | |
---|---|
Member of the Swiss Federal Council | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1 January 2003 | |
Asíwájú | Ruth Dreifuss |
President of Switzerland | |
In office 1 January 2007 – 31 December 2007 | |
Vice President | Pascal Couchepin |
Asíwájú | Moritz Leuenberger |
Arọ́pò | Pascal Couchepin |
Head of the Federal Department of Foreign Affairs | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1 January 2003 | |
Asíwájú | Joseph Deiss |
Vice President of Switzerland | |
In office 1 January 2006 – 31 December 2006 | |
Ààrẹ | Moritz Leuenberger |
Asíwájú | Moritz Leuenberger |
Arọ́pò | Pascal Couchepin |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Keje 1945 Sion |
Àwọn ọmọ | 2 |
Residence | Geneva |
{{{blank1}}} | André Calmy |
Micheline Anne-Marie Calmy-Rey (ojoibi 8 July 1945) je oloselu ara Switzerland to di olori fun Eka Ijoba Apapo fun Oro Okere — eyun, alakoso oro okere orile-ede Switzerland. O tun je ikan ninu Igbimo Ijoba Apapo Switzerland lati 2002, ati Aare ni 2007.
Igba ewe ati ikeko
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Calmy-Rey je bibi ni Sion ni ibile Valais fun Charles ati Adeline Rey. Calmy-Rey gba iwe eri ni 1963 ni St. Maurice, ati iwe eri DEA ninu sayensi oloselu ni Institut de hautes études internationales (HEI) (Graduate Institute of International Studies) ni 1968. O wole oko ni 1966 ni gba to fe André Calmy. Won ni omo meji.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |