Michelle Abueng
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kẹfà osù kaàrún ọdún 2001 | ||
Playing position | Iwájú | ||
Club information | |||
Current club | Yasa | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2019– | Yasa | ||
National team | |||
2015–2017 | Botswana U17[1][2] | ||
2017–2020 | Botswana U20[3] | ||
2019– | Botswana[4] | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Michelle Abueng tí a bí ní ọjọ́ kẹfà osù kaàrún ọdún 2001 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède Botswana kan tí ó mú ipò iwájú lórí pápá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Zambia FC Yasa FC àti ẹgbẹ́ <a href="./Bọọlu_ẹgbẹ_obinrin" rel="mw:WikiLink" data-linkid="80" data-cx="{"adapted":false,"sourceTitle":{"title":"Women's association football","thumbnail":{"source":"https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/bd/FIFA_Women%27s_World_Cup_2019_Final_-_Alex_Morgan_and_Stefanie_van_der_Gragt.jpg/80px-FIFA_Women%27s_World_Cup_2019_Final_-_Alex_Morgan_and_Stefanie_van_der_Gragt.jpg","width":80,"height":60},"description":"Association[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] football when played by women","pageprops":{"wikibase_item":"Q606060"},"pagelanguage":"en"},"targetFrom":"mt"}" class="cx-link" id="mwFw" title="Bọọlu ẹgbẹ obinrin">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin ti <a href="./Bọọlu_ẹgbẹ_obinrin" rel="mw:WikiLink" data-linkid="80" data-cx="{"adapted":false,"sourceTitle":{"title":"Women's association football","thumbnail":{"source":"https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/bd/FIFA_Women%27s_World_Cup_2019_Final_-_Alex_Morgan_and_Stefanie_van_der_Gragt.jpg/80px-FIFA_Women%27s_World_Cup_2019_Final_-_Alex_Morgan_and_Stefanie_van_der_Gragt.jpg","width":80,"height":60},"description":"Association[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] football when played by women","pageprops":{"wikibase_item":"Q606060"},"pagelanguage":"en"},"targetFrom":"mt"}" class="cx-link" id="mwFw" title="Bọọlu ẹgbẹ obinrin">orílẹ̀-ède</a> Botswana .
Ó di ẹni tí ẹgbẹ́ Zambia Yasa Queens mọ̀ nígbà tí ó ń gbábọ́ọ̀lù tako Zambia ní bi African U-17 Women's World Cup Qualifying Tournament ti ọdún 2018, ṣùgbọ́n wọn kò ní àànfàní láti buwọ́ lùú gbígbà wọlé rẹ̀ títí di ọdún 2019 nítorípé ó jẹ́ ọmọdé ní àkókò náà. [5]
Ó mi àwọ̀n pẹ̀lú àmi ayò máàrún nínú eré bọ́ọ̀lù tí ó gbá tako Namibia ní bi Ìdíje ayẹyẹ Ife àgbáyé ti àwọn Obìrin U-20 ti ọdún 2020 . [6]
Ó ṣe àkọ́kọ́ ìfarahàn ti òkè-òkun ní bi <a href="./2019_COSAFA_Women_ká_asiwaju" rel="mw:WikiLink" data-linkid="90" data-cx="{"adapted":false,"sourceTitle":{"title":"2019 COSAFA Women's Championship","description":"International football competition","pageprops":{"wikibase_item":"Q66088308"},"pagelanguage":"en"},"targetFrom":"mt"}" class="cx-link" id="mwJQ" title="2019 COSAFA Women ká asiwaju">Ìdíje</a> 2019 COSAFA Women's Championship ní ọjọ́ kinní Oṣù Kẹjọ ọdún 2019
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Competitions - WWC-Q U17 2016 - Match Details". CAF. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ "Competitions - African Qualifiers FIFA U-17 WWC-URUGUAY 2018 - Match Details". CAF. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ "Competitions - African Qualifiers FIFA U-20 WWC- FRANCE 2018 - Match Details". CAF. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ "Nachula scores eight as Zambia claim big win in Nelson Mandela Bay". COSAFA. 1 August 2019. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ Kerileng, Gaone (29 October 2020). "Michelle Abueng: Botswana's youngest export". The Botswana Gazette. https://www.thegazette.news/sport/michelle-abueng-botswanas-youngest-export/34594/#.X6hnA1NKjRY. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ Ahmadu, Samuel (30 January 2020). "'This is heartbreaking' - Valencia striker Coleman in tears after Namibia's heavy defeat". Goal. https://www.goal.com/en/news/this-is-heartbreaking-valencia-striker-coleman-in-tears/9lg5d2pp9asq1t1tfzyhumgyd. Retrieved 8 November 2020.