Michelle Attoh
Ìrísí
Michelle Attoh | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Michelle Attoh |
Orílẹ̀-èdè | Ghana |
Ẹ̀kọ́ | Unknown |
Iṣẹ́ | Òṣèré, olugbóhùn sáfẹ́fẹ́ lórí amóhùnmáwòrán |
Gbajúmọ̀ fún | Eré ṣíṣe, Olóòtú fún TV Shows |
Michelle Attoh jẹ́ òṣèré orílẹ̀ èdè Ghana kan, olugbóhùn sáfẹ́fẹ́ lórí amóhùnmáwòrán àti Alakoso fún Marketing and Events company. [1] Wọ́n bíi sí orílẹ̀ èdè Ghana sínú ẹbí ògbóǹtarìgì òṣèré orílẹ̀ èdè Ghana, Rama Brew .
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Michelle ni olóòtú Today's Woman lórí TV3 . Díẹ̀ nínú àwọn ipa mìíràn tí ó ti kópa nínú iṣẹ́ rẹ̀ ni a ṣe àkójọ sí ìsàlẹ̀.
Odun | Akọle | Ipa | Awọn akọsilẹ |
---|---|---|---|
2019 | Fix Us | Oṣere | |
Ọdun 1990-2000 | Ultimate Paradise | Oṣere | |
N/A | Home with Michelle Attoh | Olóòtú | |
N/A | Bad Luck Joe | Oṣere |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "TheBFTOnline". Michelle Attoh to host new season of Today’s Woman on TV3. June 13, 2020. https://thebftonline.com/13/06/2020/michelle-attoh-to-host-new-season-of-todays-woman-on-tv3/.