Microlophus habelii
Ìrísí
Microlophus habelii | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Subphylum: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | |
Suborder: | |
Infraorder: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | |
Irú: | M. habelii
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Microlophus habelii (Steindachner, 1876)
| |
Àwọn ibi tí a ti lè rí Microlophus habelii ní àwọn erékùṣù Galapagos | |
Synonyms | |
|
Microlophus habelii, tí wọ́n sábà mọ̀ sí alángbá àpáta Marchena jẹ́ ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti Marchena.[2]
Ìpinlẹ̀ṣẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan, habelii, dá Simeon Habel, onímọ̀ àdáyébá ọmọ jamaní-Amẹ́ríkà lọ́lá.[3]
ìṣàsọ́tọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n fí M. habelii sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kó wọn sí ẹ̀yà Tropidurus, tí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀ tẹ́lẹ̀.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Microlophus habelii.
- ↑ Benavides E, Baum R, Snell HM, Snell HL, Sites JW Jr. 2009.
- ↑ Beolens B, Watkins M, Grayson M. 2011.
Ìwé àkàsíwájú si
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Steindachner F. 1876. "Die Schlangen und Eidechsen der Galapagos-Inseln ". Zoologisch-Botanischen Gesellschaft in Wien 1876: 303-329. (Tropidurus habelii, àwọn ẹ̀yà tuntun). ( Èdè Jẹ́mánì).
Àyọkà alángbá yí jẹ́ kúkurú. Olè ran Wikipedia lọ́wọ́ lati fẹ̀ẹ́ síi. |