Microlophus koepckeorum
Ìrísí
Microlophus koepckeorum | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Subphylum: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | |
Suborder: | |
Infraorder: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | |
Irú: | M. koepckeorum
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Microlophus koepckeorum (Mertens, 1956)
| |
Synonyms | |
|
Microlophus koepckeorum, tí wọ́n mọ̀ sí Frost's iguana, jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní Chile àti Peru.[1]
Ìpinlẹ̀ṣẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan, koepckeorum, dá Hans-Wilhelm Koepcke àtí Maria Koepcke, tí wọ́n jẹ́ ọkọ àti ìyàwó, onímọ̀ ẹyẹ ọmọ orílẹ̀ èdè jamaní tí wọ́n bí sị́ Peru.
̀Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìwé àkàsíwájú si
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Mertens R. 1956. "Studien über die Herpetofauna Perus I. Zur Kenntniss der Iguaniden-Gattung Tropidurus in Peru ". Senckenbergiana Biologica 37: 101-136. (Tropidurus occipitalis koepckeorum, new subspecies, p. 117). (ní èdè jamaní).
Àyọkà alángbá yí jẹ́ kúkurú. Olè ran Wikipedia lọ́wọ́ lati fẹ̀ẹ́ síi. |