Millicent Agboegbulem
Ìrísí
Statistics | |
---|---|
Rated at | Middleweight |
Nationality | Nigerian |
Birth date | 18 Oṣù Kẹfà 1983 |
Birth place | Nigeria |
Millicent 'Milli' Agboegbulem (tí wọ́n bí ní 18 June 1983) jẹ́ afẹ̀ṣẹ́jà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń gbé ní ìlú Australia. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ ní 2018 Commonwealth Games.
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Millicent kópa nínú ìdíje àwọn afẹ̀ṣẹ́jà ti Commonwealth ti ọdún 2018. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ ní ìdíje náà.[1][2][3]
Ní oṣù kẹta ọdún 2023, Agboegbulem díje dupò oyè Australian Super Welterweight Champion pẹ̀lú Desley Robinson, ó sì borí. Ní oṣù keje ọdún 2023, Agboegbulem jìjàkadì pẹ̀lú Tayla Harris láti di oyè náà mú.[4] Harris tóbi, kò sì sí ẹni tó borí nínú ìjà pẹ̀lú rẹ̀ rí, àmọ́ Agboegbulem jáwé olúborí nínú ìdíje náà.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Boxing | Athlete Profile: Millicent AGBOEGBULEM - Gold Coast 2018 Commonwealth Games". results.gc2018.com. Retrieved 2020-11-05.
- ↑ "Boxing – Women's Middleweight (75kg) results" (in en-GB). BBC Sport. https://www.bbc.co.uk/sport/commonwealth-games/43668999.
- ↑ "Odunuga, Agboegbulem settled for bronze medals". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-13. Retrieved 2020-11-05.
- ↑ https://www.tapology.com/fightcenter/bouts/781935-harris-vs-agboegbulen-millicent-mili-agboegbulen-vs-tayla-harris
- ↑ https://www.couriermail.com.au/sport/boxing-mma/boxing-news-aflw-star-tayla-harris-suffers-gruesome-injury-in-australian-title-fight-loss-to-millicent-agboegbulen/news-story/b9050749ff2fff4ad8a0955d1352d9e8