Miriam Makeba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Miriam Makeba
Background information
Orúkọ àbísọZenzile Miriam Makeba[1]
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiMama Afrika
Occupation(s)Singer
Years active1954-2008
LabelsManteca, RCA, Mercury Records, Kapp Records, Collectables, Suave Music, Warner Bros., PolyGram, Drg, Stern's Africa, Kaz, Sonodisc
WebsiteOfficial Website

Miriam Màkébà tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù Kẹta ọdún 1932 tí ó sìn di olóògbé ọjọ́ kẹwàá oṣù kọkànlá ọdún 2008 (4 March 1932 - 10 November 2008)[2] jẹ́ akọrin àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ ènìyàn ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Gúúsù Afíríkà. Ó gba Ẹ̀bùn Grammy. Orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ tó gbajúmọ̀ ni Mama Afrika.

Igba ewe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Zenzile Miriam Makeba jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Johannesburg, Olú ìlú Gúúsù Áfíríkà. Wọ́n bí I lọ́dún ni 1932. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Swazi sangoma. Bàbá rẹ̀ kú nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́fà, orúkọ rẹ̀ Xhosa. Nígbà èwe rẹ̀, oy korin ní Kilmerton Training Institute ní Pretoria, níbi tó ti kẹ́kọ̀ọ́ fún ọdún mẹ́jọ.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Miriam Makeba official website
  2. Some sources (e.g. [1]) give 9 November as her date of death, however her official website gives 10 November