Jump to content

Mkoani

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
City map of Mkoani (Pemba)
Mkoani wharf

Mkoani jẹ́ ìlú kan ní Tansania tí ó wà ní erékùsù Pemba. Ó jẹ́ olú ìlú Pemba apá gúúsù. Mkoani ti wá di ẹ̀bádò tí ó kún jùlọ ní erékùsù Pemba látàrí ọ̀pọ̀ ọkọ̀ ojú omi tí ó wá láti Zanzibar tí ó máa ń dé síbẹ̀.[1][2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Fitzpatrick, Mary (2009). East Africa. Footscray, Victoria, Australia: Lonely Planet. p. 144. ISBN 978-1-74104-769-1. 
  2. Class, Hotel (2019-12-27). "Mkoani Photos - Featured Images of Mkoani, Pemba Island". TripAdvisor. Retrieved 2019-12-27.