Jump to content

Modupe Adeyeye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Modupe Adeyeye
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Keje 1992 (1992-07-29) (ọmọ ọdún 32)
London, England
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2011–present
TelevisionEastEnders
EastEnders: E20
Hollyoaks

Modúpé Adéyeyè (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù keje ọdún 1992)[1] jẹ́ òṣèré tí ó gbajúmọ̀ fún ipa Faith Olubunmi tí ó kó nínú eré EastEnders àti Blessing Chambers nínú eré Hollyoaks.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí sí ìlú London. Ó ti kópa nínú àwọn eré dírámà tí Our Girl, My Murder àti Doctors.[3] Ó kópa nínú eré Honeytrap ní ọdún 2014 pẹ̀lú Tosin Cole. Ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejì ọdún 2014, Adeyeye darapọ̀ mọ́ àwọn òṣèré fún eré Hollyoaks, ó sì kó ipa Blessing Chambers nínú eré náà.[4][5][6][7] Ní ọdún 2020, ó kó ipa Mischa nínú eré Surge èyí tí ilé iṣẹ́ BBC gbé kalẹ̀[8]

Àwọn Ìtọ́kàsi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Àdàkọ:Cite tweet
  2. Tina Campbell (18 February 2014). "Hollyoaks: meet new character Blessing Chamber, played by Modupe Adeyeye". Metro. http://metro.co.uk/2014/02/21/meet-new-hollyoaks-character-blessing-chamber-yes-really-4312164/. Retrieved 23 January 2020. 
  3. "Modupe Adeyeye". Sainou. Archived from the original on 21 September 2020. Retrieved 23 January 2020. 
  4. Deen, Sarah (25 April 2014). "Hollyoaks’ Blessing Chambers to reveal she used to be a man called Tyson". Metro. http://metro.co.uk/2014/04/25/hollyoaks-blessing-chambers-to-reveal-she-used-to-be-a-man-called-tyson-4709424/. Retrieved 27 April 2014. 
  5. "New character alert - Blessing Chambers". Channel 4. (Channel Four Television Corporation). Archived from the original on 28 February 2014. Retrieved 28 February 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Kilkelly, Daniel (5 February 2014). "Hollyoaks unveils new character Blessing Chamber". Digital Spy. http://www.digitalspy.co.uk/soaps/s13/hollyoaks/news/a549012/hollyoaks-unveils-new-character-blessing-chamber.html. Retrieved 5 February 2014. 
  7. "Blessing Chambers". Channel 4. Retrieved 25 February 2014. 
  8. "Modupe Adeyeye". Sainou. Archived from the original on 21 September 2020. Retrieved 23 January 2020.