Mohammed Isa Anka
Ìrísí
Mohammed Isa Anka je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o ṣiṣẹ bi Aṣoju ti o nsójú àgbègbè Anka/ Talata Mafara ti Ìpínlè Zamfara ni Àpéjọ Orilẹ-ede fun àwọn aṣòfin kẹwàá. [1] [2] [3]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://dailypost.ng/2023/02/27/jigawa-apcs-isah-anka-wins-anka-talata-mafara-federal-constituency/
- ↑ https://blueprint.ng/we-commend-tinubu-for-ensuring-10th-assembly-fully-participated-in-2024-bugetary-process-hon-anka/
- ↑ https://tribuneonlineng.com/six-emerge-unopposed-as-apc-house-of-reps-candidates-in-zamfara/